Ìtanná
Ìṣegbéringbérin oníná |
---|
Ìtanná (Electricity) ni sayensi, imo-ero, onise-ona ati àwon isele eleda to je mo bi awon adijo ina se wa ati bi won se n sanlo. Itanna n fa orisirisi isele oni-tanna, bi monamona, ina ojukan, ifasara gberingberin onina ati isanlo iwo onitanna ninu waya ina. Bakan naa, itanna gba idasile ati igbasodo iranka gberingberin onina bi awon iru radio laye.
Ninu itanna, awon adijo n se awon papa onigberingberin onina ti won n sise lori awon adijo miiran. Itanna n sele nitori orisirisi awon iru siseeda:
- adijo itanna: ini awon igbonwo abeatomu melo kan, to unso bi ibasepo onigberingberin onina won yio se ri. Awon elo ti won ti je didijo lonitanna yio je ninipa lori latowo awon papa onigberingberin onina be sini yio tun pese won.
- iwo itanna: isan awon igbonwo ti won ti je didijo lonitanna, won saba je wiwon ni eyo ampere.
- papa itanna (e wo isiseojukan onina): iru papa onigberigberin onina agaga kan ti ko soro to je dida latowo adijo itannna kan sibesibe bi ko ti le sún (eyun pe ko si ìwọ́ itanna). Papa itanna unda ipá lori awon adijo miran ti won wa nitosi re. Awon adijo ti won ba unsún na tun unpese papa onigberingberin.
- iniagbara itanna: eyi ni agbara ti papa itanna ni lati le se ise lori adijo itanna kan, eyi unsaba je wiwon ni volt.
- àwọn gbéringbérin oníná: iwo initanna unfa papa gberingberin wa, be sini papa gberingberin to unyipada unfa iwo onitanna wa.
Ninu iseero onitanna, itanna unje lilo fun:
- agbara itanna (eyi le tokasi bi okun iniagbara onitanna ba se posi tabi si okun onitanna larin asiko kan) to wa fun lilo, latodo ile-ise onitanna. Bakanna, "itanna" le je lilo bi oro fun "sisomo waya fun itanna" to tumosi isopomora isise mo ibuso agbara ina. Iru isopomora bahun fun awon alo "itanna" ni aye si papa itanna to wa ninu isopowaya itanna, ati bi be si agbara itanna.
- isiseonina da lori awon asoyipo onitanna ti won ni awon ohun inu alagbese onitanna bi awon igo adepa, awon tiransisto, awon adojuona ati awon asoyipo olodidi, ati awon oroiseona to ba sepo.
Awon isele onitanna ti je gbigbeka lati igba aye atijo, sibesibe ilosiwaju ninu sayensi re ko sele titi di orundun ketadinlogun ati kejidinlogun. Awon imulo alamuse fun itanna sibesibe si kere, yio si di opin orundun okandinlogun ki awon oniseero o to le lo ni ile-ise ati ibugbe. Igbale iyara ninu oroiseona onitanna ni asiko yi se awon ile-ise ati awujo di otun. Nitoripe itanna se lo lorisirisi ona lati pese okun gba laye mulo ninu opo imulo alainiye bi irinna, igbegbonna, itanmole, ibanisoro, ati isirokomputa. Agbara onitanna ni igbaeyin ile-ise awujo odeoni, be si ni yio ri lojowaju.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Akiyesi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Jones, D.A. (1991), "Electrical engineering: the backbone of society", Proceedings of the IEE: Science, Measurement and Technology, 138 (1): 1–10, doi:10.1049/ip-a-3.1991.0001
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Bird, John (2007), Electrical and Electronic Principles and Technology (3rd ed.), Newnes, ISBN 0-978-8556-6 Check
|isbn=
value: length (help) - Duffin, W.J. (1980), Electricity and Magnetism (3rd ed.), McGraw-Hill, ISBN 0-07-084111-X
- Edminister, Joseph (1965), Electric Circuits (2nd ed.), McGraw-Hill, ISBN 07084397X Check
|isbn=
value: length (help) - Hammond, Percy (1981), "Electromagnetism for Engineers", Nature, Pergamon, 168 (4262): 4, Bibcode:1951Natur.168....4G, ISBN 0-08-022104-1, doi:10.1038/168004b0
- Morely, A.; Hughes, E. (1994), Principles of Electricity (5th ed.), Longman, ISBN 0-582-22874-3
- Naidu, M.S.; Kamataru, V. (1982), High Voltage Engineering, Tata McGraw-Hill, ISBN 0-07-451786-4
- Nilsson, James; Riedel, Susan (2007), Electric Circuits, Prentice Hall, ISBN 978-0-13-198925-2
- Patterson, Walter C. (1999), Transforming Electricity: The Coming Generation of Change, Earthscan, ISBN 1-85383-341-X
- Sears, Francis W.; et al. (1982), University Physics (6th ed.), Addison Wesley, ISBN 0-201-07199-1
- Benjamin, P. (1898). A history of electricity (The intellectual rise in electricity) from antiquity to the days of Benjamin Franklin. New York: J. Wiley & Sons.
Ajapo ode
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- "One-Hundred Years of Electricity", May 1931, Popular Mechanics
- Illustrated view of how an American home's electrical system works
- Electricity around the world
- Electricity Misconceptions
- Electricity and Magnetism Archived 2015-12-01 at the Wayback Machine.
- Understanding Electricity and Electronics in about 10 Minutes
- World Bank report on Water, Electricity and Utility subsidies