Richard Phillips (oníṣòwò ojú omi)
Ìrísí
Ọ̀gá ọkọ̀ Richard Phillips | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kàrún 1955 Winchester, Massachusetts, U.S. |
Orílẹ̀-èdè | ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà |
Iṣẹ́ | oníṣòwò ojú omi, akọ̀wé |
Gbajúmọ̀ fún | ọ̀gá ọkọ̀ ti MV Maersk Alabama nígbà Ìfipá Gba Maersk Alabama ní Ọdún 2009 |
Richard Phillips (bíi Ọjó kẹrindínlógún Oṣù karún Ọdún 1955[2]) jẹ́ oníṣòwò ojú omí ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí ó jẹ́ ògá ọkọ̀ MV Maersk Alabama nígbà tí àwọn ajalèlókun tí Somalia fẹ́ já ọkọ̀ náà gbà ní Oṣù kẹrin Ọdún 2009.
Ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Phillips ní Massachusetts,[3] ó kàwé jade ní ilé ìwé Winchester High School ní Ọdún 1973.[4]Phillips wọ ilé ìwé gíga University of Massachusetts Amherst, ó sì pinu lati kà òfin gbogboògbò ṣùgbón wọ́n gbe sí Massachusetts Maritime Academy, níbi tí ó ti kàwé jade ni Ọdún 1979.[5] Nígbà tó ń kàwé lọ́wọ́ ó ń ṣisẹ́ awakọ̀ ní Boston.[6]
Àwọn ìtọkasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Orr, Jimmy (May 10, 2009). "Obama meets Captain Richard Phillips and then plays hoops". The Christian Science Monitor.. https://www.csmonitor.com/USA/Politics/The-Vote/2009/0510/obama-meets-captain-richard-phillips-and-then-plays-hoops. Retrieved 14 October 2013.
- ↑ Captain Phillips (2013) historyvshollywood.com
- ↑ "Resolution Praising Captain Richard Phillips Of Vermont Passes". Retrieved 2013-09-03.
- ↑ "Friends Describe Hostage Captain as Seaman's Seaman With Keen Sense of Humor". Retrieved 2013-09-03.
- ↑ Kennedy, Helen (9 April 2009). "Who is Richard Phillips? Captain of the Maersk Alabama and a hero on the high seas". New York Daily News. https://www.nydailynews.com/news/us_world/2009/04/09/2009-04-09_who_is_richard_phillips_captain_of_the_maersk_alabama_and_a_hero_on_the_high_sea.html. Retrieved 2013-09-03.
- ↑ "Profile: Captain Richard Phillips". Retrieved 2013-09-03.