Jump to content

C++

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìdá lórí C++.

C++ (ti an pe ni "cee pilus pilus") o je kiko ti o duro, form ofe language, orisirisi-paradigm, ti a compili, iwulo gbogboede programming. A o ma pe ni ede aarin, nitori wipe o ni awon irinse |ede ti o ga]] ati ede ti o kere.[1] Bjarne Stroustrup ni eni ti o da ede yi sile lati odun 1979 ni Bell Labs gege bi ilosiwaju fun ede C. Eyin ti oruko ipinle re n je C pelu kilaasisi, won so ede naa ni C++ ni odun 1983.[2]

C++ je ikan lara awon ede ti o gbajumo[3][4] pelu apilication domain ti o ni sisitem software ninu (gege bi Microsoft Windows), application software, device drivers, embedded software, high-performance server ati client applications, pelu software idaraya gege bi video games.[5] ai moye akojopo ni o man pese C++ ofe ati propreitary compiler software, pelu GNU Project, Microsoft, Intel ati Embarcadero Technologies. C++ ti je arikoshe ti o ni agbara fun awon ede programming yoku tio gbajumo , e yin ti o gbajumo ju C# ati Java.

A tun ma nlo C++ fun hardware design, ni ibi ti a ti koko se apejuwe design ni C++, ti a se ijiroro re, architecturally constrained, ati gbigba aye lati da register-transfer level hardware description language via high-level synthesis. [6]


  1. Herbert Schildt (1 August 1998). C++ The Complete Reference Third Edition. Osborne McGraw-Hill. ISBN 978-0078824760. 
  2. Bjarne Stroustrup (7 March 2010). "C++ Faq: When was C++ Invented". ATT.com. Archived from the original on 26 September 2011. Retrieved 16 September 2010. 
  3. "Programming Language Popularity". 2009. Retrieved 16 January 2009. 
  4. "TIOBE Programming Community Index". 2009. Retrieved 3 August 2011. 
  5. "C++ Applications". Archived from the original on 2011-05-11. Retrieved 2011-10-27. 
  6. "What's CvSDL?". https://www.cvsdl.com/: cvsdl. Archived from the original on 29 May 2010. Retrieved 8 March 2010. CvSDL was introduced in 2003 as a C++ class framework with Verilog features that worked like a Verilog simulator. Since then it has been revamped to be a standard-compliant HDL simulator, currently supporting Verilog. It is capable of cosimulating with SystemC. It can be used just as an HDL simulator or to generate executable specifications written in Verilog and SystemC on the hardware side and in C, C++ and SystemC on the software side.